Eks 34:32 YCE

32 Lẹhin eyinì ni gbogbo awọn ọmọ Israeli si sunmọ ọ: o si paṣẹ gbogbo ohun ti OLUWA bá a sọ lori òke Sinai fun wọn.

Ka pipe ipin Eks 34

Wo Eks 34:32 ni o tọ