Eks 35:1 YCE

1 MOSE si pè apejọ gbogbo ijọ awọn ọmọ Israeli, o si wi fun wọn pe, Wọnyi li ọ̀rọ ti OLUWA palaṣẹ pe, ki ẹnyin ki o ṣe wọn.

Ka pipe ipin Eks 35

Wo Eks 35:1 ni o tọ