Eks 35:19 YCE

19 Aṣọ ìsin wọnni, lati sìn ni ibi mimọ́, aṣọ mimọ́ wọnni fun Aaroni alufa, ati aṣọ awọn ọmọ rẹ̀, lati ma fi ṣe iṣẹ alufa.

Ka pipe ipin Eks 35

Wo Eks 35:19 ni o tọ