Eks 39:29 YCE

29 Ati ọjá ọ̀gbọ olokùn wiwẹ́, ati ti aṣọ-alaró, ti elesè-àluko, ati ti ododo, oniṣẹ abẹ́rẹ; bi OLUWA ti fi aṣẹ fun Mose.

Ka pipe ipin Eks 39

Wo Eks 39:29 ni o tọ