Eks 40:38 YCE

38 Nitoriti awọsanma OLUWA wà lori agọ́ na li ọsán, iná si wà ninu awọsanma na li oru, li oju gbogbo ile Israeli, ni gbogbo ìrin wọn.

Ka pipe ipin Eks 40

Wo Eks 40:38 ni o tọ