Eks 5:10 YCE

10 Awọn akoniṣiṣẹ enia na si jade, ati awọn olori wọn, nwọn si sọ fun awọn enia na, pe, Bayi ni Farao wipe, Emi ki yio fun nyin ni koriko mọ́.

Ka pipe ipin Eks 5

Wo Eks 5:10 ni o tọ