Eks 6:14 YCE

14 Wọnyi li olori ile baba wọn: awọn ọmọ Reubeni akọ́bi Israeli; Hanoku, ati Pallu, Hesroni, ati Karmi: wọnyi ni idile Reubeni.

Ka pipe ipin Eks 6

Wo Eks 6:14 ni o tọ