Eks 6:16 YCE

16 Wọnyi si li orukọ awọn ọmọ Lefi ni iran wọn; Gerṣoni, ati Kohati, ati Merari: ọdún aiye Lefi si jẹ́ mẹtadilogoje.

Ka pipe ipin Eks 6

Wo Eks 6:16 ni o tọ