Eks 7:11 YCE

11 Nigbana ni Farao pẹlu pè awọn ọlọgbọ́n ati awọn oṣó: awọn pẹlu, ani awọn alalupayida Egipti, si fi idán wọn ṣe bẹ̃ gẹgẹ.

Ka pipe ipin Eks 7

Wo Eks 7:11 ni o tọ