Eks 7:2 YCE

2 Iwọ o sọ gbogbo eyiti mo palaṣẹ fun ọ: Aaroni arakunrin rẹ ni yio si ma sọ fun Farao pe, ki o rán awọn ọmọ Israeli jade ni ilẹ rẹ̀.

Ka pipe ipin Eks 7

Wo Eks 7:2 ni o tọ