Eks 7:24 YCE

24 Gbogbo awọn ara Egipti si wàlẹ yi odò na ká fun omi mimu; nitoriti nwọn kò le mu ninu omi na.

Ka pipe ipin Eks 7

Wo Eks 7:24 ni o tọ