Eks 8:19 YCE

19 Nigbana ni awọn alalupayida wi fun Farao pe, Ika Ọlọrun li eyi: ṣugbọn àiya Farao le, kò si fetisi ti wọn; bi OLUWA ti wi.

Ka pipe ipin Eks 8

Wo Eks 8:19 ni o tọ