Eks 9:10 YCE

10 Nwọn si bù ẽru ninu ileru, nwọn duro niwaju Farao; Mose si kù u si oke ọrun; o si di õwo ti o ntú jade pẹlu ileròro lara enia ati lara ẹran.

Ka pipe ipin Eks 9

Wo Eks 9:10 ni o tọ