Eks 9:16 YCE

16 Ṣugbọn nitori eyi pãpa li emi ṣe mu ọ duro, lati fi agbara mi hàn lara rẹ; ati ki a le ròhin orukọ mi ká gbogbo aiye.

Ka pipe ipin Eks 9

Wo Eks 9:16 ni o tọ