Eks 9:24 YCE

24 Yinyin si bọ́, iná si dàpọ mọ́ yinyin na, o papọ̀ju, irú rẹ̀ kò si ri ni gbogbo ilẹ Egipti lati ìgba ti o ti di orilẹ-ède.

Ka pipe ipin Eks 9

Wo Eks 9:24 ni o tọ