Eks 9:30 YCE

30 Ṣugbọn bi o ṣe tirẹ ni ati ti awọn iranṣẹ rẹ, emi mọ̀ pe sibẹ, ẹnyin kò ti ibẹ̀ru OLUWA Ọlọrun.

Ka pipe ipin Eks 9

Wo Eks 9:30 ni o tọ