Eks 9:7 YCE

7 Farao si ranṣẹ, si kiyesi i, ọkanṣoṣo kò kú ninu ẹran-ọ̀sin awọn ọmọ Israeli. Àiya Farao si le, kò si jẹ ki awọn enia na ki o lọ.

Ka pipe ipin Eks 9

Wo Eks 9:7 ni o tọ