Isa 13:13 YCE

13 Nitorina emi o mu ọrun mì titi, ilẹ aiye yio si ṣipò rẹ̀ pada, ninu ibinu Oluwa awọn ọmọ-ogun, ati li ọjọ ibinu gbigbona rẹ̀.

Ka pipe ipin Isa 13

Wo Isa 13:13 ni o tọ