Isa 13:22 YCE

22 Awọn ọ̀wawa yio si ma ke ninu ãfin wọn, ati dragoni ninu gbọ̀ngàn wọn daradara: ìgba rẹ̀ si sunmọ etile, a kì yio si fa ọjọ rẹ̀ gùn.

Ka pipe ipin Isa 13

Wo Isa 13:22 ni o tọ