Isa 13:3 YCE

3 Emi ti paṣẹ fun awọn temi ti a yà si mimọ́, emi ti pe awọn alagbara mi pẹlu fun ibinu mi, ani awọn ti nwọn yọ̀ ninu ọlanla mi.

Ka pipe ipin Isa 13

Wo Isa 13:3 ni o tọ