Isa 14:21 YCE

21 Mura ibi pipa fun awọn ọmọ rẹ̀, nitori aiṣedẽde awọn baba wọn; ki nwọn ki o má ba dide, ki nwọn ni ilẹ na, ki nwọn má si fi ilu-nla kun oju aiye.

Ka pipe ipin Isa 14

Wo Isa 14:21 ni o tọ