Isa 15:2 YCE

2 On ti goke lọ si Bajiti, ati si Diboni, ibi giga wọnni, lati sọkun: Moabu yio hu lori Nebo, ati lori Medeba: gbogbo ori wọn ni yio pá, irungbọ̀n olukulùku li a o fá.

Ka pipe ipin Isa 15

Wo Isa 15:2 ni o tọ