Isa 17:7 YCE

7 Li ọjọ na li ẹnikan yio wò Ẹlẹda rẹ̀, ati oju rẹ̀ yio si bọ̀wọ fun Ẹni-Mimọ Israeli.

Ka pipe ipin Isa 17

Wo Isa 17:7 ni o tọ