Isa 19:23 YCE

23 Li ọjọ na ni opopo kan yio wà lati Egipti de Assiria, awọn ara Assiria yio si wá si Egipti, awọn ara Egipti si Assiria, awọn ara Egipti yio si sìn pẹlu awọn ara Assiria.

Ka pipe ipin Isa 19

Wo Isa 19:23 ni o tọ