Isa 19:4 YCE

4 Oluwa, Oluwa awọn ọmọ-ogun wipe, Awọn ara Egipti li emi o fi le oluwa onrorò li ọwọ́; ọba ti o muna yio ṣe akoso wọn.

Ka pipe ipin Isa 19

Wo Isa 19:4 ni o tọ