Isa 21:17 YCE

17 Iyokù ninu iye awọn tafàtafà, awọn alagbara ninu awọn ọmọ Kedari yio dinkù: nitori Oluwa Ọlọrun Israeli ti wi i.

Ka pipe ipin Isa 21

Wo Isa 21:17 ni o tọ