Isa 22:12 YCE

12 Ati li ọjọ na ni Oluwa, Oluwa awọn ọmọ-ogun yio pè lati sọkun, ati lati ṣọ̀fọ, ati lati fá ori, ati lati sán aṣọ ọ̀fọ.

Ka pipe ipin Isa 22

Wo Isa 22:12 ni o tọ