Isa 23:9 YCE

9 Oluwa awọn ọmọ-ogun ti pete rẹ̀, lati sọ irera gbogbo ogo di aimọ́, lati sọ gbogbo awọn ọlọla aiye di ẹ̀gan.

Ka pipe ipin Isa 23

Wo Isa 23:9 ni o tọ