Isa 28:19 YCE

19 Niwọn igbati o ba jade lọ ni yio mu nyin: nitori ni gbogbo owurọ ni yio rekọja, li ọsan ati li oru: kiki igburo rẹ̀ yio si di ijaiyà.

Ka pipe ipin Isa 28

Wo Isa 28:19 ni o tọ