Isa 28:28 YCE

28 Akara agbado li a lọ̀; on kò le ma pa a titi, bẹ̃ni kò fi kẹkẹ́-ẹrù fọ́ ọ, bẹ̃ni kì ifi awọn ẹlẹṣin rẹ̀ tẹ̀ ẹ.

Ka pipe ipin Isa 28

Wo Isa 28:28 ni o tọ