Isa 29:19 YCE

19 Ayọ̀ awọn onirẹlẹ yio bí si i ninu Oluwa, ati inu awọn talaka ninu awọn enia yio si dùn ninu Ẹni-Mimọ Israeli.

Ka pipe ipin Isa 29

Wo Isa 29:19 ni o tọ