Isa 29:24 YCE

24 Awọn pẹlu ti o ṣinà nipa ẹmi, oye yio wá yé wọn, ati awọn ti nsọ bótibòti yio kọ́ ẹkọ́.

Ka pipe ipin Isa 29

Wo Isa 29:24 ni o tọ