Isa 32:11 YCE

11 Warìri, ẹnyin obinrin ti o wà ni irọra; ki wahala ba nyin ẹnyin alafara: ẹ tú aṣọ, ki ẹ si wà ni ihòho, ki ẹ si dì àmure ẹgbẹ́ nyin.

Ka pipe ipin Isa 32

Wo Isa 32:11 ni o tọ