6 Nigbana li awọn arọ yio fò bi agbọ̀nrin, ati ahọ́n odi yio kọrin: nitori omi yio tú jade li aginju, ati iṣàn omi ni ijù.
Ka pipe ipin Isa 35
Wo Isa 35:6 ni o tọ