Isa 37:19 YCE

19 Nwọn si ti sọ awọn òriṣa wọn sinu iná: nitori ọlọrun ki nwọn iṣe, ṣugbọn iṣẹ ọwọ́ enia ni, igi ati òkuta: nitorina ni nwọn ṣe pa wọn run.

Ka pipe ipin Isa 37

Wo Isa 37:19 ni o tọ