Isa 37:32 YCE

32 Nitori lati Jerusalemu ni iyokù yio jade lọ, ati awọn ti o sala lati oke Sioni wá: itara Oluwa awọn ọmọ-ogun yio ṣe eyi.

Ka pipe ipin Isa 37

Wo Isa 37:32 ni o tọ