Isa 38:17 YCE

17 Kiyesi i, mo ti ni ikorò nla nipò alafia: ṣugbọn iwọ ti fẹ́ ọkàn mi lati ihò idibàjẹ wá: nitori iwọ ti gbe gbogbo ẹ̀ṣẹ mi si ẹ̀hin rẹ.

Ka pipe ipin Isa 38

Wo Isa 38:17 ni o tọ