Isa 39:8 YCE

8 Nigbana ni Hesekiah wi fun Isaiah pe, Rere ni ọ̀rọ Oluwa ti iwọ ti sọ. O si wi pẹlu pe, Alafia ati otitọ́ yio sa wà li ọjọ mi.

Ka pipe ipin Isa 39

Wo Isa 39:8 ni o tọ