Isa 40:14 YCE

14 Tali o mba a gbìmọ, tali o si kọ́ ọ lẹkọ́, ti o si kọ́ ọ ni ọ̀na idajọ, ti o si kọ́ ọ ni ìmọ, ti o si fi ọ̀na oye hàn a?

Ka pipe ipin Isa 40

Wo Isa 40:14 ni o tọ