Isa 40:22 YCE

22 On ni ẹniti o joko lori òbíri aiye, gbogbo awọn ti ngbe ibẹ si dabi ẹlẹngà; ẹniti o ta ọrun bi ohun tita, ti o si nà wọn bi àgọ lati gbe.

Ka pipe ipin Isa 40

Wo Isa 40:22 ni o tọ