Isa 40:27 YCE

27 Ẽṣe ti iwọ fi nwi, Iwọ Jakobu, ti iwọ si nsọ, Iwọ Israeli pe, Ọ̀na mi pamọ kuro lọdọ Oluwa, idajọ mi si rekọja kuro lọdọ Ọlọrun mi?

Ka pipe ipin Isa 40

Wo Isa 40:27 ni o tọ