Isa 41:28 YCE

28 Nitori mo wò, kò si si ẹnikan; ani ninu wọn, kò si si olugbimọ̀ kan, nigbati mo bere lọwọ wọn, kò si ẹniti o le dahùn ọ̀rọ kan.

Ka pipe ipin Isa 41

Wo Isa 41:28 ni o tọ