Isa 41:4 YCE

4 Tali o ti dá a ti o si ti ṣe e, ti o npè awọn iran lati ipilẹṣẹ̀ wá? Emi Oluwa ni; ẹni-ikini, ati pẹlu ẹni-ikẹhìn; Emi na ni.

Ka pipe ipin Isa 41

Wo Isa 41:4 ni o tọ