Isa 42:11 YCE

11 Jẹ ki aginjù ati ilu-nla ibẹ gbé ohùn wọn soke, iletò wọnni ti Kedari ngbé: jẹ ki awọn ti ngbé apáta kọrin, jẹ ki wọn hó lati ori oke-nla wá.

Ka pipe ipin Isa 42

Wo Isa 42:11 ni o tọ