Isa 42:19 YCE

19 Tani afọju, bikoṣe iranṣẹ mi? tabi aditi, bi ikọ̀ mi ti mo rán? tani afọju bi ẹni pipé? ti o si fọju bi iranṣẹ Oluwa?

Ka pipe ipin Isa 42

Wo Isa 42:19 ni o tọ