Isa 44:9 YCE

9 Asan ni gbogbo awọn ti ngbẹ ere; nkan iyebiye wọn ki yio si lerè; awọn tikala wọn li ẹlẹri ara wọn: nwọn kò riran, bẹ̃ni nwọn kò mọ̀; ki oju ba le tì wọn.

Ka pipe ipin Isa 44

Wo Isa 44:9 ni o tọ