Isa 45:12 YCE

12 Mo ti dá aiye, mo si ti da enia sori rẹ̀; Emi, ani ọwọ́ mi, li o ti nà awọn ọrun, gbogbo awọn ogun wọn ni mo si ti paṣẹ fun.

Ka pipe ipin Isa 45

Wo Isa 45:12 ni o tọ