Isa 46:2 YCE

2 Nwọn bẹ̀rẹ, nwọn jumọ tẹriba; nwọn kò le gbà ẹrù na silẹ, ṣugbọn awọn tikala wọn lọ si igbèkun.

Ka pipe ipin Isa 46

Wo Isa 46:2 ni o tọ