Isa 51:15 YCE

15 Ṣugbọn emi Oluwa Ọlọrun rẹ ti o pin okun ni iyà, eyi ti ìgbi rẹ̀ nhó; Oluwa awọn ọmọ-ogun ni orukọ rẹ̀.

Ka pipe ipin Isa 51

Wo Isa 51:15 ni o tọ