Isa 51:18 YCE

18 Kò si ẹnikan ninu gbogbo awọn ọmọ ọkunrin ti o bí lati tọ́ ọ; bẹ̃ni kò si ẹniti o fà a lọwọ, ninu gbogbo awọn ọmọ ọkunrin ti on tọ́ dàgba.

Ka pipe ipin Isa 51

Wo Isa 51:18 ni o tọ